
Gospel music minister and songwriter, Temiloluwa releases a brand new single titled “My Prayer“.
I urge you to restore your faith and speak with the father as you listen and download this soul reviving single “MY PRAYER”.
Download, Listen and Share;
[maxbutton id=”1″ url=”https://cldup.com/DFDMIEyeag.mp3?download=Temiloluwa%20-%20My%20Prayer.mp3″ text=”DOWNLOAD” ]
LYRICS!
Eledumare moti duro lenu ona mogboju mi soke gege bi omo ileri ti o fise wase temi Funmi
Temiloluwa My Prayer
[Chorus]
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi }2*
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi 2*
[Verse 1]
Bi iranlowo eda badopin talole gbami ooo,Iwo mo sa towa oluwa wa ran mi lowo
Mogbeke mi Le oo baba setemifunmi
Mogbeke mi le oo olorun gbo adura miii
[Chorus]
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi }2*
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi 2*
[Verse 2]
Mo mope o lo lese jahovah,kosi ohun ti Iwo kole se
Oku lasaru ojo keta oti ra,oti ru sugbon sibe ojidide ,Awon Ise iyanu to tise talole kawan tan Setemifunmi
Gege bi omo ileri timo je
Wa se temifunmi
Chorus Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi }2x
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi 2x
Bi ireti badopin ti kosi oluranlowo Iwo nikan lo le se
Bi ireti badopin,afi Iwo afi Iwo nikan lo le bamiseeeeeeee
CONNECT:-
Instagram: @temiloluwamusic
Facebook: Temiloluwa Music







