
JayMikee born Joshua Mike-Bamiloye, son of Mike-Bamiloye releases a powerful sound captioned “Dide” featuring Tee Worship.
The song, Dide is done in the Yoruba language of Nigeria. It was featured on ENOCH the movie.
Press Play, Listen & Download below;
LYRICS:
Dide!
Ẹmi Oluwa Jehova mbẹ lara mi (Dide)
Nitoriti o fi àmi oróro yàn mi (Dide)
Lati wasu fun awọn òtosi (Dide)
O ti rán mi wá lati ṣe awotan oo (Dide)
Gbogbo awọn onirobinujẹ ọkàn (Dide)
Ati gbogbo awon alainireti (Dide)
Kede idasilẹ fun awọn igbekun (Dide)
Ati isile tubu fun awon ounde (Dide)
JayMikee Dide
Dide eee eh dide ooo (Dide), dide o Kristiani Oloogun (Dide)
Kristiani maa ti wa simi o
Ni angeli re wi
Ni aarin ota lo waa, maa sora
Maa sora, maa sora (Dide)
Ogun orun apaadi (Dide)
Ti a ko ri sugbon won ko ara won jo (Dide)
Won nso e,won nso e, won nso e (Dide)
Dide o, Dide oo, Dide ooo (Dide)
Maa sora Kristiani (Dide)
Igbagbo yi, O gbodo di mu(Dide)
Dide o, Dide o (Dide)
Dide ooo (Dide)
Dide eee eh dide ooo (Dide), dide o Kristiani Oloogun(Dide)
Kristiani Oloogun (Dide)
Dide, Dide, Dide, dide






